APC kéde àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ ìpolongo ìdìbò 2019

APC kéde àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ ìpolongo ìdìbò 2019

Oríṣun àwòrán, @APCUKingdom

Àkọlé àwòrán,

APC kéde àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ ìpolongo ìdìbò 2019

Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC ti fi orúkọ awọn ọmọ igbimọ wọn fún ipolongo idbo aarẹ lọdun 2019.

Ninu atẹjade ti olugbaninimọran fun aarẹ, Femi Adeshina fi sita lọjọ kejidinlọgbọn oṣu kejila ọdun 2018, wọn kede ẹni ti yoo jẹ alaga, ajumọ jẹ alaga, awọn igbakeji alaga àti awọn adari ni ipele ẹlẹkun jẹkun.

Bakan naa ẹgbẹ APC, yan awọn gbajugbaja oniṣowo nla, Aliko Dangote ati Femi Otedola ggẹ bi olugbaninimọran wọn fun ipolongo idibo yan aarẹ.

ALAGA

Aarẹ Muhammadu Buhari

AJUMỌ JẸ ALAGA

Asiwaju Bola Ahmed Tinubu

IGBAKEJI ALAGA

1. Igbakeji Aarẹ, Ọjọgbọn Yemi Osinbajo.

2. Alaga ẹgbẹ oṣelu APC, Comrade Adams Oshiomole

IGBAKEJI ALAGA NI ILA OORUN

Sẹnetọ George Akume

IGBAKEJI ALAGA NI GUUSU

Sẹnetọ Ken Nnamani

OLUDARI AGBA

Họn. Rotimi Amaechi

IGBAKEJI OLUDARI AGBA (IṢẸ ṢIṢE)

Sẹnetọ A.O. Mamora

IGBAKEJI OLUDARI AGBA (IṢAKOSO)

Arch. Waziri Bulama

AKỌWE

1. Adamu Adamu

2. Dele Alake

AWỌN ADARI ẸKUN

a. Iwọ Oorun Ariwa (North West): Senator Aliyu M. Wamakko

b. Ila Oorun Ariwa (North East): Senator Muh'd Ali Ndume

c. Ariwa Aarin gbungbun (North Central): Senator Abdullahi Adamu

d. Iwọ Oorun Guusu (South West): Sola Oke, SAN

e. Ariwa Guusu (South East): Sharon Ikeazor

f. Guusu-Guusu (South South): Senator Godswill Akpabio

Àkọlé fídíò,

Wòlíì Kasali sọrọ nípa awuyewuye pé o lè ìyàwó rẹ̀ jáde nílé

ẸKA NJẸKA

a. Oludari, ẹgbẹ alatilẹyin Buhari (Buhari Support Groups) - Dr. Mahmoud Mohammed

b. Oludari, Eto ibaraẹnisọrọ (Strategic Communications) - Festus Keyamo, SAN

a. Igbakeji Oludari - Abike Dabiri- Erewa

c. Oludari ikansiraẹni (Contact & Mobilization) - Hadiza Bala Usman

a. Igbakeji Oludari ẹkun Guusu -Victor Eboigre

b. Igbakeji Oludari ẹkun Ariwa - Senator Bashir Nalado

d. Oludari alamojuto eto idibo, (Election Planning & Monitoring) - Babatunde Raji Fashola, SAN

a. Igbakeji Oludari I- Baba Kura Abba Jato

b. Igbakeji Oludari II-Chief Emani Ayiri

e. Oludari Iṣẹ Oniruuru, Logistics - Dr. Pius Odubu

a. Igbakeji Oludari- Senator Umanah Umanah

b. Igbakeji Oludari II- Nasiru Danu

f. Oludari, Iṣewadii aato (Policy Research & Strategy)- Ọjọgbọn Abdulrahman Oba

a. Igbakeji Oludari- Ọjọgbọn A.K. Usman

g. Oludari ọrọ to kan ọdọ (Youth Mobilization)- Hon. Tony Nwoye pẹlú iranwọ olori ọdọ APC Sadiq

a. Igbakeji Oludari ẹkun Ariwa- Amofin Ismaeel Ahmed

b. Igbakeji Oludari ẹkun Guusu - Jasper Azuatalam

h. Oludari Iṣakoso (Admin)- Onari Brown

a. Igbakeji Oludari I- Chris Hassan

b. Igbakeji Oludari II- Abubakar Magaji Gasau

i. Oludari ọrọ obinrin (Women Mobilization)- Woman Leader Salamatu Baiwa

a. Igbakeji Oludari ẹkun Ariwa - Binta Mu'azu

b. Igbakeji Oludari ẹkun Guusu - Adejoke Orelope Adefulire j. Oludari ọrọ abo (Security) - Gen. A. . Dambazzau

a. Awọn Igbakeji Oludari - Brigadier General Gambo and Mr. U. Ukoma

k. Oludari ẹka Ofin (Legal) - Emeka Ngige, SAN

a. Igbakeji Oludari- Ọjọgbọn Maman Lawan Yusufari

l. Oludari Iṣẹ Ode (Field Opertaions)- Mallam Nuhu Ribadu

M. Oludari eto isuna (Finance) - Wale Edun

Igbakeji Oludari ….Alhaji Adamu Fadan

AWỌN AGBANINIMỌRAN AGBA FUN AARẸ

1. Igbakeji Aarẹ, Prof. Yemi Osinbajo.

2. Asiwaju Bola Ahmed Tinubu

3. Senator Ahmed Lawan (Senate Leader)

4. Họn. Femi Gbajabiamila ( Leader of the House )

5. Alaga ẹgbẹ oṣelu APC, Comrade Adams Oshiomole

6. Alhaji Aliko Dangote.

7. Ọgbẹni Femi Otedola

AWỌN ỌMỌ IGBIMỌ

1. Chief Bisi Akande

2. Chief John Oyegun

3. Senator Ita Enang

4. Gbogbo Sẹnetọ APC to ṣi wa lori oye

5. Gbogbo Gomina APC to ṣi wa lori oye atawọn to ti kuro

6. Gbogbo ọmọ ẹgbẹ APC nile igbimọ aṣoju ṣofin

7. Gbogbo ọmọ igbimọ amuṣẹya APC

8. Gbogbo adari obinrin lẹlẹkun jẹkun

AWỌN ALAMOJUTO IPINLẸ

1. Awọn Gomina yoo jẹ alakoso ipinlẹ wọn

2. Awọn oludije Gomina APC lawọn ipinlẹ ti kii ṣe ti ẹgb APC yoo jẹ alakoso ipinlẹ wọn