2019 Elections: Fọ́tò ìpolóngo ìbò ẹgbẹ́ òṣèlú APC àkọ́kọ́ ní Uyo

Ẹgbẹ́ oṣèlú APC pín àsìá fún gbogbo olùdíje gómìnà fún ọdún 2019 ní ẹkún Gúúsù-Gúúsù.

ìpolóngo ìbò ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Àkọlé àwòrán,

APC kede Muhammadu Buhari gẹgẹ bii alaga igbimọ ipolongo idibo yan aarẹ wọn lowurọ ọjọ ẹti ki ipolongo to bẹrẹ.

Àkọlé àwòrán,

Aarẹ Muhammadu Buhari

Àkọlé àwòrán,

Awọn gomina APC tẹwọ gba asia ẹgbẹ

Àkọlé àwòrán,

Alaga ẹgbẹ oṣelu APC, Adams Oshiomọlẹ gan ko gbẹyin ninu ijo nibi ipolongo naa

Àkọlé àwòrán,

Bola Ahmed Tinubu ni ajumọ jẹ alaga

Àkọlé àwòrán,

Aarẹ Buhari pẹlu awọn oloye ẹgbẹ oṣelu APC

Àkọlé àwòrán,

Awọn obinrin ẹgbẹ naa jẹwọọ pe awọn peju pesẹ sibẹ

Àkọlé àwòrán,

Yoruba ni ọwọ gẹngẹ nii ṣaaju ijo lo difa fun awọn igbọwọ ijo yii ati idunnu