Amina Zakari: Mi ò tan mọ́ ààrẹ Buhari rárá o!

Amina Zakari: Mi ò tan mọ́ ààrẹ Buhari rárá o!

Amina Zakari sọ pé ojuṣe oun ko ni lati ka abajade esi ibo rara.

O fi kun un wi pe "ojuṣe mi ni lati rii daju pe ibudo kika wa ni ipo to dara fun ohun ti yoo waye nibẹ".

"Alaga ajọ eleto lo ni ojuṣe ati ka gbogbo abajade esi idibo loju gbogbo eniyan".