Ngendera Albert: Mi ò fẹ́ kí wọ́n máa pa ọ̀ọ̀nì ni mo ṣe ń rà wọ̀n

Ngendera Albert: Mi ò fẹ́ kí wọ́n máa pa ọ̀ọ̀nì ni mo ṣe ń rà wọ̀n

Ijẹlọkan ki ẹmi awọn ọọni ma nu mọ lo mu ki Ngendera Albert máà kó wọn ya sọtọ ni orilẹede Burundi lati maa ṣe itọju wọn.

Ọ maa n fi sọkan lati wa aaye to to lati boju to wọn pẹlu iwọn ounjẹ ti yoo yo wọn lasiko.

Bi o ba de ibi kan to rii ti wọn pa ọ̀ọ̀ni, a maa ba a lọkan jẹ pupọ.

O ja fun ẹtọ ẹranko, o ni ko tọ ki wọn maa fi awọn ẹranko ṣe ounjẹ gẹgẹ bi wọn ti ń ṣe lorilẹede Burundi.

Nitorinaa, o pe e lati maa fi owo gọbọi ra wọn ki wọn ṣi le wa laaye.