'Abínibí ní ọfọ̀ àti àyájọ́ jẹ́ fún mi'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Abìjà: Bàbá mi fi iṣẹ́ ọdẹ ti ń pa lémi lọ́wọ́ ni nítorí babaláwo ni

Abija-wara-bí-ẹkun ṣalaye ohun tó bi orukọ rẹ fun BBC Yorùbá.

Alhaji Yẹkinni Ajilẹyẹ lo kọ ere Ọ̀pá Ajé to gbé Abija sita gẹgẹ bii alagbára.

Tajudeen Oyewọle ṣalaye ibẹrẹ rẹ fun BBC pe ọfọ, ayajọ, agbara jẹ ajogunba ninu ilé fun oun nitori pe idile babalawo ni wọn bi oun sí.

O ni ọdẹ ti n pa ni oun kii ṣe ọdẹ lasan rara.

Abija gba awọn oṣere asiko yii imọran ki wọn ma tori ẹdẹ ba ẹ̀ẹ̀dẹ̀ jẹ́.

O ni ki wọn gbiyanju lati maa gbe sinima to n kọ atewe atagba lẹkọ sita loorekoore.