Ahmed Musa padanu ìyá rẹ̀ lẹyin aisan ranpẹ

Ahmed Musa Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ahmed Musa dabira Nàìjírìa nínú ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé lorílẹ́èdè Russia

Agbabọọlu ọmọ Naijiria Ahmed Musa ti padanu iya rẹ bayi.

O fi iroyin naa to awọn ọmọ Naijiria leti lori Twitter ni Ọjọbọ niga to ni "Ọjọ ibanuje ni ọjọ yii jẹ fun aye mi. Mo ti padanu iya mi."

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionObasanjo: Atiku kìí se Áńgẹ́lì, àmọ́ yóò se dáadáa ní ìlọ́po méjì ju Buhari lọ

O ti sọ tẹlẹ pe iya oun ṣaarẹ ko to di pe o ku.

Image copyright @ahmedMusa718
Àkọlé àwòrán iya ni wura iyebiye
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko.

Ni ana ni o fi aworan iya rẹ sori Twitter ninu eyi to fi n ki pe ki o dara le.

Image copyright @Ahmedmusa718
Àkọlé àwòrán abiyamọ ni gbogbo aye n gbadura ko duro jẹun ọmọ

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption2019 Elections: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionỌ̀tọ̀ ni nkan tí wọ́n sọ fún ẹbí rẹ̀, iṣẹ́ aṣẹ́wó ni wọ́n fi n ṣe