Femi Falana: kò yé kí ìdájọ́ òfin yàtó síra wọn ni Naijiria

Ogbontarigi agbẹjọrọ, Femi Falana sọ iyatọ idajọ adigunjale atawọn alagbara ni Naijiria.

Femi Falana sọrọ nipa owo ilu tijọba ti Buhari ti gba sẹyin pé ara ilu ko mọ ohun ti wọn ṣi koo dani fun.

O mẹnuba agbara ofin ati bi o ṣe yẹ ki a loo ninu iṣejọba alagbada to yaranti.

Agbẹjọro yii sọ pataki ninu eto idajọ ti ko ṣègbè falagbara ati mẹkunnu ninu eyi ti iṣejọba tiwantiwa a fi goke agba ni Naijiria.