Ìrìn àjò sí ilẹ̀ Yuropu: Àìríṣẹ́ṣe ló mú àwọn ọ̀dọ̀ fẹ̀mí wọn wéwu

Ìrìn àjò sí ilẹ̀ Yuropu: Àìríṣẹ́ṣe ló mú àwọn ọ̀dọ̀ fẹ̀mí wọn wéwu

Ipinlẹ Edo ni iwadi fihan pe awọn to n ṣe atipo lọ si ilẹ Yurupo ti pọju ni orilẹede Naijiria.

Bakan naa ni ipinlẹ Delta to wa lẹgbẹ Edo si keji ninu awọn ipinlẹ ti wọn ti n fi eeyan ṣe iṣowo lọ si ilẹ okere ni Naijiria.

Ọpọ ni wọn ti da pada sile lẹyin ti ba awọn ẹshọ ori omi ti ajọ EU fi sori okun pade ninu irinajo wọn silẹ Yuropu.