Nigeria 2019 Election: Àwọn jàndùkú sun ohun èlò níná l'Oṣun

Nigeria 2019 Election: Àwọn jàndùkú sun ohun èlò níná l'Oṣun

O kere tan awọn agunbanirọ meji lo farapa lẹyin ti awọn janduku kọlu wọn ti wọn si sun ohun elo idibo ati ẹrọ amunawa ti wọn lo fun idibo nina nipinlẹ Osun.

Ọga ajọ eleto idibo INEC nipinlẹ Osun Ọgbẹni Sẹgun Agbaje to ba BBC Yoruba sọrọ ṣalaye pe ibo kika ti n lọ lọwọ nigba ti iṣẹlẹ ọhun ṣẹlẹ.