'Mama Tobi', Ọkùnrin tó ń ṣe bí obìnrin nítorí àtijẹ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Oluwakaponeski ní ọmọogun ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni òun tẹ́lẹ̀ kí òun tó di aláwàdà

Oluwatobi Ọbatẹdo ni orukọ ti obi sọ ọ, oluwakaponeski lawọn ololufẹ rẹ loju opo Instagram mọ ọ si, 'Mama Tobi'si ni ere alawada rẹ.

Ki ni o sun Oluwatobi, sọja ilẹ Amẹrika di alawada ere Yoruba lori ayelujara?

Paapaa julọ, ki lo sọ ọ di ẹni to n mura bi Obinrin lati pa awọn ololufẹ rẹ lẹrin?

Labare ree...

ìfipábánilòpọ̀: Má dákẹ́ - Oluwaseun

Wọ́n ta ère Ọ̀ṣun Osogbo sí Togo - Bàbá Ọṣun figbe ta

World TB Day: "Ó dùn mí jù pé ń kò rí ọmọ mi fún ọdún kan"

'Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ló gbégbà orókè nínú ìwà jẹgudujẹra ní Nàìjíríà'

Oshisko twins, àwọn 'ìbejì' tó ń dẹ́rìn ín p'òṣónú

Mo fẹ́ sálọ torí ìpèníjà àkójọpọ̀ èsì ìbò gómìnà Ọyọ - Kọ̀misánà INEC l‘Ọyọ

Àwọn àmì tó fi mọ̀ pé wọn ń fipá bá ọmọdébìnrin rẹ lòpọ̀

Ìyá àgbà Ọlayinka, arúgbó tó ń ṣoge bí omidan

World water day: Ẹrin Ijesa, Ọ̀ṣun Oṣogbo, àwọn ibùdó ìgbafẹ́ omi tí ó yẹ kí o mọ̀

Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á

Èmi ṣì ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọṣun-Oyetọla

"Ìlú mímọ́ nibí, wọn kò gbọdọ̀ bímọ, sin òkú àbí ẹran síbẹ̀"