Pope kisses feet of South Sudan leaders
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Póópù Francis kúnlẹ fí ẹnu ko ẹsẹ̀ àwọn adarí orílẹ̀ède South Sudan

Olori ijọ Aguda, Poopu Francis fi ẹnu ko ẹsẹ awọn adari orilẹede South Sudan nigba ti wọn lọ ki ni ibudo rẹ ni Vatican.

O ni oun fẹ bẹ wọn lati gba alaafia laaye ni oun ṣe gbe igbesẹ naa.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: