Wọn ti ti ọja oba ilu naa, ti wọn si ti si ọja lọ si ibo miran.

Wọn ti ti ọja oba ilu naa, ti wọn si ti si ọja lọ si ibo miran.

Awọn ara ilu Ọwọ se mọ wi pe ọba awọn ti waja ni, lẹyin ti wọn si ọja ọba lọ si ibomiran.