Ibadan Tanker Fire Accident: Ènìyàn méji ló kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ agbépo

Ibadan Tanker Fire Accident: Ènìyàn méji ló kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ agbépo

Ọga agba ileeṣẹ pana-pana ni ipinlẹ Ọyọ sọ pe ọwọ ko ti i tẹ awakọ epo to gbina ni opopona marosẹ Ibadan si Eko.

L'ọsan Ọjọbọ, ọjọ kejidinlogun oṣu Kẹrin ni ijamba naa waye lori afara to wa ni adugbo Saw-Mill nilu Ibadan, to si mu ẹmi eniyan meji lọ.