'A fẹ́ kí àwọn sẹ́nétọ̀, mínísítà gba ẹlòmíì láàyè'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

May 29: Àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ irú àwọn adarí tí wọ́n ń fẹ́

Ṣaaju eto ibura wọle ti yoo waye ni ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu karun ọdun 2019 lorilẹede Naijiria, awọn araalu ti n sọ iru awọn adari ti wọn fẹ ki aarẹ yan lati ba a ṣiṣẹ.

Ni saa to kọja, ọpọ sọ iei ti wọn fi fẹran iṣẹ ti awọn aṣofin kan atawọn minisita ṣe ti wọn si fẹ ki wọn tẹsiwaju.

Ni ida keji awọn mii ni ayipada lawọn n fẹ latọdọ aarẹ Buhari.