Ṣé ó láyà? óyá dára wò pẹ̀lú àwọn òwe Yorùbá

  • Omi tó tán lẹ́yìn ẹja ló sọọ́ di èrò ìṣaasùn
  • A kì í fi ọjọ́ kan bọ́ ọmọ tó rù.
  • Bí ẹ̀mí bá wà, ìrètí ń bẹ
  • Òkò tí a bá bínú jù, kì í pa ẹyẹ
  • Bí a kò bá rí ẹni bá là ọ̀là kì í yá.
  • Nínú ìkòkò dúdú ni ẹ̀kọ funfun ti ń jade
  • Ìwà rere lẹ̀ṣọ́ ènìyàn
  • Ojú tó rí ibi tí kò fọ́ ire ló ń dúró dè
  • A kì í mọ̀ọ́ gún mọ̀ọ́ tẹ̀ kí iyán ewùrà má lẹ́mọ
  • Ẹni tó láṣọ tí ò léèyàn ìhòhò ló wà

Related Topics