Awọn ọmọ Naijiria gboriyin fun Super Eagles
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

AFCON 2019: Ọmọ Nàijíríà rọ Super Eagles lati tubọ sápa wọn pẹlú Madagascar

Ọ̀pọ̀ ọmọ Nàìjíríà ló tí ń ṣe sàdánkata káre sí ikọ Super Eagles lóri ìfẹsẹ̀wọnsẹ tó wáye lóni láàrin àwọn ati Guinea. Nígbà ti awọn kan ní èróngbà àwọn ni pé ó yẹ ki Super Eagles fakọyọ ju bí wọn ṣe se lọ nítori ọ̀pọ́ ànfani ni wọ́n sọnu, sibẹ̀ yiniyini kẹ́ni le ṣe omíràn ni ọ̀rọ̀ náà yoo jẹ ni àwọn kan ń sọ

Wọn ni ó ṣe pàtàki kí wọ́n lọ túra mu láti jáwe olúbori nítori pe àwọn ni ìgbàgbọ́ pé wan yóó de ipile to kayin si aṣekagbá ninu idije náà.