'A fẹ́ kúrò ní Larubawa nítorí à kò gba ẹ̀sìn'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Iraq, Palestine wà nínú orílẹ̀-èdè mẹ́wàá tí ìwádìí BBC ti wáyé

O le ni oluwadii ẹgbẹrun mẹedọgbọn ti wọn ṣiṣẹ iwadii naa fun BBC.

Ida kan ninu ida mẹta awọn eeyan Larubawa ati ariwa Afrika ni wọn fẹ ko kuro ni ilu wọn.

BBC Arabic ati Arab Barometer ṣe iṣẹ iwadii lati fi mọ ero awọn eniyan yii nipa ẹsin ti wọn n sìn.

Ọpọ awọn ti wọn fọrọ wa lẹnuwo gba pe lootọ lawọn n gbe ni ilẹ Larubawa ṣugbọn igbagbọ wọn ninu ẹsin n dinku sii ni.

Kọmputa ni wọn fi ṣe iṣẹ iwadii naa kakiri orilẹ-ede mẹwaa.