Iya Woli Asafa Salamot: Gbọ́ àsọtẹ́lẹ̀ látẹnu Small Mummy tó fi àwàdà dárà
Iya Woli Asafa Salamot: Gbọ́ àsọtẹ́lẹ̀ látẹnu Small Mummy tó fi àwàdà dárà
Maleebu ki ara rẹ de gongo, ẹyin ẹ̀ṣà ògbín dá?
Odọmọde adẹrin pa òṣónú lori ayelujara Instagram ni BBC Yoruba gbalejo ẹ.
Aṣafa Salamot ti gbogbo aye n pe ni Iya Wolii, Small Mummy lo fi talẹnti rẹ dara ki awọn eeyan le rẹrin gbagbe iṣoro wọn.
- Wòlíì ni ọmọ táà bá bí ni ago kan géérégé ni...Bàbá tó bí Ooni Adeyeye Ogunwusi sọ àṣírí àkọsẹ̀jayé rẹ̀
- 'Ọọ̀nì ńlá méjì ní wọ́n jọ ń gbé nínú iyàrá'
- #BBCGOVDEBATE: Ọgbọ́n ìmọ̀ àti òye ní ń ò fi ṣe ìjọba- GNI
- Anthony Joshua ni ìwúrí ọmọ ọdún méje yìí
- Children's Day: Àwọn ọmọdé tó ń ṣe bẹbẹ láwùjọ Afíríkà
Small Mummy sọ bo ṣe n kawe papọ mọ iṣẹ alawada ti ọkan ko di ikeji lọwọ.
Iya Wolii ni ọdun kẹta rẹ ree ti oun ti n ṣe iṣẹ awada to n dẹrin pa awọn eniyan Naijiria.
Aṣafa Salamọt gba awọn ewe bii tirẹ nimọran pe ki wọn gbọran si obi wọn lẹnu laiyọ iwe kika silẹ.
Maleebu ni ki awọn ọmọde ma ṣe ri talẹnti wọn mọlẹ ki wọn gbe ogo ti Olorun fun wọn sita.