Kíni àwọn ọ̀dọ́ Naijiria ń fẹ́ lọ́wọ́ àwọn mínísta tuntun?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọn ọ̀dọ́ Naijiria ti sọ̀rọ̀ síta lórí ohun ti wọ́n ń retí lọ́dọ̀ minista tuntun

Ọpọ n reti ki aarẹ Buhari kede iṣẹ onikaluku ninu awọn minista tuntun ti ilé ṣe ayẹwo fun.

Loni ọjọru, ọjọ kọkanlelogun, oṣu kẹjọ ọdun yii ni wọn yoo bura fun awọn minsita ti ile igbimọ aṣofina papọ ti ṣe ayẹwo fun.

BBC Yoruba jade sita lọ fi ọrọ wa awọn ọdọ lẹnu wo lori ohun ti wọn n reti lọdọ awọn minista tuntun yii.

Ọpọ nakn ti wọn mẹnuba jẹ édun ọkan onikaluku lasiko yii.