A kò lè padà sí South Africa mọ́ láè- ọ̀kan lára àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Xenophobia: Awọn ọmọ Naijiria n sọ ohun tó kàn lẹ́yìn ìpadàbọ̀ wọn

Ijọba lo ku ti a n bẹ bayii- ọmọ Naijiria

Awọn ọmọ Naijiria ti wọn koju ikọlu sawọn ajoji to waye ni South Africa ti n pada sile lati alẹ ana.

BBC Yoruba ba ninu wọn sọrọ to mẹnuba ibẹru rẹ bayii to ti pada sile lati wa tun igbesi aye rẹ bẹrẹ lọtun.