Oyo Tribunal: Bó ṣe lọ rèé nílé ẹjọ́ lẹ́yìn tí adájọ́ ní Seyi Makinde lo borí ìbò

Bó ṣe lọ rèé nílé ẹjọ́ lẹ́yìn tí adájọ́ ní Seyi Makinde lo borí ìbò .

APC àti PDP ti wa sọ ìgbésẹ̀ tó kàn lẹ́yìn ìdájọ́ èsì ìbò gómìnà Ọyọ.

Koda, se ni ọpọ eeyan n fo fun ayọ lẹyin idajọ to ni Seyi Makinde lo moke ninu ibo gomina nipinlẹ Ọ́yọ.