Ààrẹ Túnisia kú sẹyin odi lẹ́ni ọdun mẹtalélọ́gọ́rin

Ben Ali Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ààrẹ Túnisia kú sẹyin odi lẹ́ni ọdun mẹtalélọ́gọ́rin

Ààrẹ Tunisia nígbà kan rí President Zine el-Abidine Ben Ali tí kú sí ẹ̀yin odi lẹ́ni ọdun mẹ́tàlélọ́gọ́rin.

Ben Ali tó dari orílẹ̀-ede náà fún ọdún mẹ́talélógun, sùgbọ̀n gbogbo ìlú mọ̀ọ́ si ẹni to mu ìlọsíwáju ba ètò ọ̀rọ̀ ajé orilẹ̀-èdè náà.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Mo fọ kọ́mú, pátá, ògiri ilé lórí 200,000 láìlèfọhùn lórílẹ̀èdè Oman'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionSouth Africa: Àwọn ọmọ Nàìjíríà tó kù ní ìjọba SA ń kó ọ̀pọ̀ tó fẹ́ wále sí ọgbà ẹ̀wọ̀n

Sùgbọ́n ọ̀ps lo n náwọ àtako nítori ó n tako òṣèlú awa ara waàti ìwà àjẹbánu.

Ní ọdun 2011, wan le kuro nílu pèlú ìfẹ̀honu han, èyi lo si far rogbodiyan lorisirisi ni ààrin àwọn ẹya Arab.