Yollywood: Ǹjẹ́ ìwọ mọ àwọn ẹbí òṣèré sinimá Yorùbá yii?

Ẹwo àkójọpọ̀ àwòrán àwọn òèré Nollywood níbi tí wọ́n ti ń gbáfẹ́ pẹ̀lú ẹbí wọn.

Sanyeri Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Afonja Olaniyi ti wọn tun n pe ni Sanyeri, jẹ ọkan gboogi ninu awọn osere ti n panilẹrin ninu fiimu.
Antar Laniyan Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Ọkan gboogi ni ẹka Nollywood ni gbajugbaja oṣere ti wọn pe ni Antar Laniyan.
Lukman Raji Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Oṣere ni tọkọ-taya Lukman Raji ati iyawo rẹ, Aminatu Papaapa.
Madam Saje Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Oṣerebinrin Fausat Balogun ti wọn maa n pe ni Madam Sajẹ ti sisẹ ribiribi ni ẹka Yollywood.
Yinka Quadri Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Ti ẹ ba n wa oṣere to n ṣiṣẹ takuntakun, Yinka Quadri ni ki ẹ kan si.
Kamilu Kompo Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Adekola Tijani (Kamilu Kompo) ree pẹlu Iyawo ati ọmọ rẹ.
Jide Kosọkọ Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Agba ọjẹ ninu oṣere, Jide Kosọkọ ti ni ọmọọmọ ninu isẹ tiata lorilẹede Naijiria
Akin Olaiya Image copyright Others
Àkọlé àwòrán Akin Olaiya re e pẹlu idile re nibi ti wọn ti n gbafẹ.

Awọn aworan yii wa lati Google ati oju opo ikansiraẹni awọn osere wọn yii,