Ìran tí Primate Ayodele rí ṣáájú ìdìbò Kogi àti Bayelsa rèé!
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kogi àti Bayelsa: Primate Ayodele sọ àsọtẹ́lẹ̀

Ohun to maa ṣẹlẹ ni mo sọ- Primate Ayodele

Oluṣoagutan Ayodele Babatunde to jẹ oludasilẹ ijọ INRI Evangelical Spiritual Church ti a si mọ ọ fun ọpọlọpọ asọtẹlẹ lorilẹ-ede Naijiria sọrọ lori abajade idibo ipinlẹ Kogi ati Bayelsa ni nkan bii oṣu kan sẹyin pe'...