Trump impeachment: Trump kò fìdí janlẹ̀ tán, àmọ́ níbo ni yóò jásì?
Trump impeachment: Trump kò fìdí janlẹ̀ tán, àmọ́ níbo ni yóò jásì?
Ọjọ kejidinlogun, oṣu Kejila ni ile aṣoju-ṣofin ilẹ̀ Amẹrika dibo yọ Aarẹ orilẹede naa, Donald Trump nipo.
Ẹsun meji to nii ṣe pẹlu aṣilo ipo ati titako iwadii ile aṣofin ni wọn fi kan an.
Awọn aṣofin yẹ aga iṣakoso mọ Trump nidii lootọ, ṣugbọn ko fi idi janlẹ patapata. Bawo wa lo ṣe ṣeeṣe ki wọn o yọ eeyan nipo, ko si tun máa ṣakoso?
Ẹkunrẹrẹ alaye re e ninu fidio yii.