Christmas: Ẹni ti ọdun ba ti bá láyé yẹ kó dúpẹ́

Christmas: Ẹni ti ọdun ba ti bá láyé yẹ kó dúpẹ́

Odun keresimesi wọle de wẹre

Ẹni ti ọdun ba ti ba laye ni ko ṣọpẹ ni awọn agba ilẹ Yoruba maa n wi.

BBC Yoruba ki gbogbo ọmọ lẹyin Kristi ku oriire ọdun Keresi ti o wọle de wẹrẹ yii pe, pataki ìbí Jesu a wa si imuṣẹ lori koowa.

Oriṣiriṣi orin ni ede oniruuru ni awọn eeyan fi maa n kọ orin Keresimesi kaakiri agbaye.

BBC Yoruba jade ni ki awọn eniyan kọ orin keresi to wu wọn,

E wo bi ohun awọn eeyan ṣe n ja geere ti wọn n ṣajọyọ ìbí Jesu!

Takọtabo lo n yọ ayọ Olugbala ti a bi fun wa nitori alaafia awa ẹda