Christmas: Jesu ni ọjọ́ ọ̀la àti ibi ìyanu mi- Jaga

Christmas: Jesu ni ọjọ́ ọ̀la àti ibi ìyanu mi- Jaga

Ibanujẹ àti aisan dopin laye yin lorukọ Jesu- Jaga

Olorin Emi, Testimony Jaga to ṣe ọmọ alade wura to logo kọrin keresi loriṣiiriṣii fun igbadun gbogbo yin.

Adura pọ lẹnu Testimony Jaga, o fede fọ wure fawọn eniyan pe ọdun keresi a yabo.