Stephen Sotonwa: Gbajúgbajà oníròyìn wọlẹ̀ sùn

Posi ti wan sin Stepen si
Àkọlé àwòrán,

Stephen Sotonwa: Gbajúgbajà oníròyìn wọlẹ̀ sùn

Okú gbájugbaja oníroyin pẹ̀lú Orange FM to ku ninu ìjànba ọkọ to wáye laipe yii ti wọ káàlẹ sùn lónìí.

Stepen Sotonwa ti gbogbo ènìyàn mọ si Sweet Steve ni wọ́n sìn si ilé rẹ̀ ni Imafon, Akure, ní ìpínlẹ̀ Ondo.

Ọ̀pọ̀ àwọn èèyànn jankanjankan lo peju sibi ìsìku náà to fi mọ àwọn alabasiṣẹ́ pọ àti àwọn ẹbi àti ọ̀rẹ Sweet Steve lo péju sibẹ̀.

Sotonwa ẹni ọdun márùnlélọ́gbọ̀n jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀, o kàwe gboye ni University Ado Ekiti to si n ba Orange FM ṣiṣẹ̀ ti o si maa n ṣe àkoso Orange Cafe àti Lunch Grove ni OSRC TV.

O fi ìyàwó, ọmọ meji, òbi, ẹgbọ́n àti aburo silẹ sáye lọ

Àkọlé àwòrán,

Stephen Sotonwa: Gbajúgbajà oníròyìn wọlẹ̀ sùn

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán,

Stephen Sotonwa: Gbajúgbajà oníròyìn wọlẹ̀ sùn