Ọ̀pọ̀ ìgbà tí ẹsẹ̀ rẹ ti gùn síì láì mọ̀ rẹ̀

"Ẹsẹ̀ wa ti yípadà. Láàrin ogójì ọdún, ẹsẹ̀ wa ti gùn síi ní ìlọ́po méjì".

Lati igba ti wọn ti da bata si aye, awọn yii gbagbọ pe o n ṣe akoba fun ẹsẹ. Lona wo?

Bakan naa ohun mii ti wọn gbagbọ pe o n ṣakoba fun ẹsẹ ni iru iṣẹ ti awọn eeyan n ṣe lode oni eyi ti wọn n jokoo ṣee lọpọ igba.

"Koda ninu ile, ọpọlọpọ nkan la n joko ṣe bayii".

Wọn tun mẹnu ba Ìdí tí ẹsẹ̀ awọn eeyan kan lagbaye fi pẹlẹbẹ. Ṣé ẹ jẹ́ ọ̀kan nínú wọn?

Wọn ni ru ẹsẹ bayii le ni ipa lara iduro wa o si le fa wahala si ibi ti awọn egungun ti pade tabi ẹyin eeyan.