Wo àwọn àdúgbò tí ìpínlẹ̀ Eko ti fòfin de ọ̀kadà àti Marwa

Image copyright @others
Àkọlé àwòrán A ko ni faaye gba gigun ọkada loju ọna marosẹ mọ nipinlẹ Eko

Ijọba ipinlẹ Eko ti fofin de awọn ọkada ati marwa pe ki wọn yee rin ni awọn agbegbe kọọkan titi awọn a fi fẹnuko lori igbesẹ to ku.

Eyi yoo din awọn ọna ti ọkada n gba rin ku kaakiri ipinlẹ Eko.

Ọpọlọpọ igba lo jẹ pe ọkada ati marwa ni awọn oṣiṣẹ, ontaja ati ẹni toju ba n kan maa n saaba fi ọkada ati marwa rirnirnajo wọn nitori sunkẹrẹ-fakẹrẹ Eko.

O le ni miliọnu mọkanlelogun awọn eniyan to n gbe ni ipinlẹ Eko.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionFarms to You: Irú ajílẹ̀ wo ló yẹ fún lílò lásìkò yìí- Aisha

Wo awọn ibi ti ọkada ati ko ni le de mọ bayii ni ipinlẹ Eko

Awọn opopona Marosẹ:1. Opopona Marosẹ Eko si Ibadan Lagos Ibadan Expressway2. Opopona Marosẹ Apapa Oshodi Expressway3. Opopona Marosẹ Oworoshoki Oshodi Expressway4. Opopona Marosẹ Lagos Ikorodu Expressway5. Opopona Marosẹ Lagos Abeokuta Expressway

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionSuper touch: Roller Blader ni mí láti ọdún mẹ́jọ sẹ́yìn

6. Babangida Bouleverde7. Opopona Marosẹ Eti-Osa Lekki Epe Expressway8. Opopona Marosẹ Lagos Badagry Express9. Funsho Williams Avenue10. Agege motor Road11. Eti-Osa Lekki Coastal Road

Wo awọn afara ti okada ati marwa ko nile rin nibẹ mọ1. Iyana-Ipaja Bridge, Ijọba ibilẹ Agege / Alimosho

2. Dopemu Bridge, Ijọba ibilẹ Agege / Alimosho3. Airport/Ikeja Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja 4. Agege Motor Road / Oshodi Loop, Oshodi, Ijọba ibilẹ Ikeja / Mushin 5. Mushin / Isolo Link Bridge, Ijọba ibilẹ Mushin Oshodi

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Wo àwọn àdúgbò tí ìpínlẹ̀ Eko ti fòfin de ọ̀kadà àti Marwa

6. Dorman Long Bridge Ijọba ibilẹ Surulere / Lagos Mainland 7. Ojuelegba Bridge, Ijọba ibilẹ Surulere / Lagos Mainland 8. National Stadium Flyover, Ijọba ibilẹ Surulere

9. Iganmu / Funsho Williams Bridge Ijọba ibilẹ Surulere

10. Apapa - Iganmu Bridge Ijọba ibilẹ Surulere

Ọọ̀ni obìnrin, Lúwòó Gbàgídà rèé, akọni tó ń gun ọkùnrin ní ẹṣin rìn

Ẹ̀yin ẹ máà wò ó, ó ṣeéṣe kí APC túká lẹ́yìn ìṣèjọ́ba Buhari!

Àwọn ará South-Africa yarí nítorí torí gbọ̀ngàn kọ̀ ìgbéyàwó abo-sábo

Mo kàn fẹ́ fi ọmọ tó sọnù gba owó lọ́wọ́ Sọtitobire ni - Afurasí

11. Apapa - Ijora Link Bridge, Ijọba ibilẹ Apapa/Lagos Mainland

12. Liverpool Bridge, Apapa, Ijọba ibilẹ Apapa 13. Mile 2 Bridge Loop, Amuwo-Odofin, Ijọba ibilẹ Amuwo-Odofin 14. Okota (Cele)/Ijesha Link Bridge Ijọba ibilẹ Mushin / Oshodi-Isolo 15. Apakun/Apapa-Oshodi Bridge Network, Ijọba ibilẹ Mushin / Oshodi / Isolo

Atiku náà kéde àtìlẹ́yìn rẹ̀ fún ẹ̀ṣọ́ alábòò Amọtẹkun

Obìnrin tó lówó jùlọ ní Africa 'ja orílẹ̀-èdè rẹ̀, Angola lólè' fi kó ọ̀rọ̀ jọ ni

Lalong, Tambuwal, Ganduje ni ilé ẹjọ́ gíga jùlọ kéde bíi gómìnà ìpínlẹ̀ wọn

Àǹfààní wo ló wà nínú Brexit fún Nàìjíríà àtàwọn orílẹ́-èdè Afíríkà?16. Ikorodu Road / Anthony Clover leaf Bridge Ijọba ibilẹ Somolu / Ikeja 17. Trade Fair Flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ojo 18. Festac / Amuwo-Odofin Link Bridge Ijọba ibilẹ Amuwo Odofin 19. 2 Flyover bridges along Alhaji Masha Rd, Ijọba ibilẹ Surulere20. Ojota Clover Leaf Bridge, Ijọba ibilẹ Kosofe / Ikeja

21. Ogudu Bridge Ijọba ibilẹ Kosofe

22. 3rd Mainland Bridge, Ijọba ibilẹ Lagos Island / Mainland / Somolu 23. Maryland flyover Ijọba ibilẹ Ikeja / Somolu

24. Ikeja / General Hospital flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja 25. Kodesho Bridge, Oba Akran, Ikeja, Ijọba ibilẹ Ikeja

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionHepatitis: A kò leè kóo nípa dídìmọ́ ara ẹni

26. Opebi Link Bridge, Ikeja Ijọba ibilẹ Ikeja 27. Sheraton-Opebi Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Ikeja 28. Jibowu/Yaba flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Mainland 29. Carter Bridge Lagos, Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Mainland 30. Bariga-Ifako Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe31. Apapa -OShodi Expressway / Alapere Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe32. Bariga / Oworonshoki Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Wo àwọn àdúgbò tí ìpínlẹ̀ Eko ti fòfin de ọ̀kadà àti Marwa

33. Apapa - Oshodi Expressway / 3rd Mainland Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe 34. Apapa - Oshodi Expressway / 3rd mainland Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe 35. 3rd mainland / Oworonshoki Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Kosofe 36. Eko Bridge Lagos Island / Lagos Mainland 37. Apongbon flyover, Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island 38. Cowry Bridge (Officers Mess) Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island / Eti-Osa.39. McWen Bridge (Bonny camp) Ijọba ibilẹ Ikeja Eti-Osa.40. Marina / Ikoyi Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island / Eti-Osa41. Ikoyi / Obalende Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Eti-Osa.

Ọkùnrin tó yí orúkọ padà sí Muhammadu Buhari ṣ'ayẹyẹ ìsọmọlórúkọ ní Kano

Uganda ti bẹrẹ ìgbésè láti fi ikú ṣefàjẹ fún ẹní bá ṣe ìgbéyàwó akọ si akọ ati abo si abo

Okunrin kan kú lójijì lẹ̀yin ọjọ̀ díẹ̀ to jẹ milionu kan dọ́là

Afurasi onisowo ibọn wọ gau agbofinroAwọn ọna miran:Ni ijọba ibilẹ Agege1. Oba Ogunji Road2. Old Abeokuta Road3. Capital Road4. Alfa Nla Road5. Oko-Oba Road6. Akilo Street7. Agunbiade Road8. Ogba Road9. Ipaja Road10. Maricas Road

Ọkùnrin kan kú si ìyárá ìtura

BBC 100 Women 2019: ọ̀pọ̀ obìnrin ilẹ̀ Afirika ń gbàràdá!

Leon van Biljon dí èrò ọrun nípasẹ̀ Kìnìún rẹ̀

Iṣẹ́ ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ Seth Ator tó yìnbọn pa ọ̀pọ̀ èèyàn ní Texas ni- ọlọ́pàá

11. Oyewole Road12. Arigbanla Street13. Dopemu Road14. Oke-koto Road15. Oniwaya Road16. Adebisi Awosoga Street17. Old Ota Road18. Ijaiye Road19. Akin Doherty Road20. Amoo Street21. Pen Cinema Round About22. Surulere Street23. Agbedeji Street24. Ayige Street25. Sule Street26. Ashipa Street27. Salawu Street

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionOndo disability: Kò sí ẹni tí àkàndá kò lè ya ilé rẹ̀- Ayọdele