Balogun Fire: Àwọn òǹtàjà figbe ta pé owó alájẹṣẹ́kù làwọn fi ra ọjà tó jóná

Ina tun jo ọ̀ja Balogun

Lasiko ti wọ̀n n ba BBC Yoruba sọrọ, awọn ontaja ni ọja Balogun ni kii se epo pẹ́troolu ti wọ̀n n rọ̀ sinu gẹ́nẹ́ratọ to n sisẹ lọwọ lo fa isẹlẹ naa.

Fidio naa ree:

Àkọlé fídíò,

Balogun Fire: Àwọn òǹtàjà figbe ta pé owó alájẹṣẹ́kù làwọn fi ra ọjà tó jóná

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Awọn ontaja yii, ti wọn n wa ẹkun mu, wa rawọ ẹbẹ si ijọba ipinlẹ Eko lati pese ileesẹ panpana si ọja ọhun lati tete dena ijamba ina to n fi ojoojumọ waye nibẹ.