Amotekun: Fatomilola ní gaga ọwọ̀ làwọn baba wa fi ń ṣọ́ ilé, òyìnbó ló sọ wá di ọ̀lẹ

Amotekun: Fatomilola ní gaga ọwọ̀ làwọn baba wa fi ń ṣọ́ ilé, òyìnbó ló sọ wá di ọ̀lẹ

Ilumọọka agba osere tiata kan, Peter Fatomilola ti fọwọ gbaya pe agbekalẹ ikọ alaabo Amotekun yaayi lasiko yii tori agbara oogun lawọn baba wa fi n daabo bo ara wọn laye atijọ.

Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, Fatomilola ni awọn baba wa kii se ilẹkun si ẹnu ọna ile, amọ gaga ọwọ mẹẹdogun ti to lati koju ole.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

O fikun pe igba tawọn oyinbo de ni awọn sọja ati ọlọpa de, ti a ko si lee fi ilana ibilẹ daabo bo ara wa mọ, ta wa di ọdẹ ati ọlẹ.