Emir of Kano: Àwọn àwòrán Sanusi nígbà tó ṣì wà lórí oyè bíi Emir

Àwọn àwòrán mọ́kànlá Lamido Sanusi lẹ́nu iṣẹ́ kí wọ́n tó yẹ àga mọ nídì.

Sanusi

Oríṣun àwòrán, DESIGNED BY STUDIO

Àkọlé àwòrán,

Sanusi, Emir kẹrinla ilu Kano nibi ayẹyẹ kan

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Emir ana, Sanusi ati aarẹ ilẹ Ghana, Nana Akufo Addo

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Muhammadu Sanusi keji pẹlu Sultan Muhammad Sa'ad Abubakar nibi aṣeyẹ kan.

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Sanusi joye Emir lẹyin baba to bi baba rẹ, Sanusi kinni, ti wọn rọ loye bakan naa.

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Emir ana, Sanusi pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari.

Oríṣun àwòrán, EMIHD KANO EMIRATE

Àkọlé àwòrán,

Sanusi wa lori alefa gẹgẹ bi Emir fun nkan bi ọdun mẹfa.

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Emir ana, Sanusi ati ọgbẹni Nitin, lati Skline Unirversity, Kano.

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO EMPIRE

Àkọlé àwòrán,

Sanusi pẹlu awọn eeyan.

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Sanusi ati onimọ nipa ẹsin Musulumi, Mufti Ismael Menk

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Sanusi nigab to ṣi wa lori apere

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM / KANO KINGDOM

Àkọlé àwòrán,

Sanusi nibi ayẹyẹ kan ki ijọba kano to rọ ọ loye