Yemi Elesho, ìlúmọ̀ọ́ká adẹ́rínpòṣónú jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí 'Ṣé o láyà?'

Yemi Elesho, ìlúmọ̀ọ́ká adẹ́rínpòṣónú jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí 'Ṣé o láyà?'

Ilumọọka adẹrinpoṣonu ni Yẹmi Ẹlẹṣọ, amọṣa lori eto Se o laya tosẹ yii, o da bẹbẹ pẹlu awọn ibeere wa gbogbo.

Ibeere loriṣiriṣi ni o dojukọ lori eto tọtẹ yii, bi o tilẹ jẹ wi pe ẹnu yii naa ko jẹ ki Yẹmi o gbadun sibẹ, o jẹwọ ara rẹ pe ẹnu nikan kọ loun ni o, oun mọ nipa aṣa ati iṣe Yoruba daadaa.