Coronavirus: Wo bí àwọn ará Ibadan ṣe n ṣe lásìkò Coronavirus yìí

Bi àwọn kan ṣe n ní òye síi lórí ààbò lásìkò arun Coronavirus yii ni àwọn míràn kò bìkítà tó!.

Àkọlé àwòrán,

Ẹ gba mi! Eeyan meloo lori ọkada yii ni Ibadan lasiko Coronavirus to yẹ ki gbogob wa maa ṣọra yii

Àkọlé àwòrán,

Baba Elẹran àti awon onibara wọn ni wọn duro gbágbá lẹ́gbẹ ara wọn lọja ni Ibadan

Àkọlé àwòrán,

Awọn ọlọkada ati marwa lo n ko ero bi adaba ti ko naani a n kun igbẹ yii!

Àkọlé àwòrán,

Awọn ọlọkada lo kunlẹ gbagba yii ti wọn ṣetan lati gbe awọn ero

Àkọlé àwòrán,

Awọn onimọto naa n ko ero wọn bi wọn ṣe fẹ nigboro Ibadan bayii

Àkọlé àwòrán,

Awọn ero ree lọkunrin lobinrin ti wọn n duro ti ara wọn lati gba owo ni banki ifowopamọsi.

Àkọlé àwòrán,

Awọn ero lo kun inu kẹkẹ Marwa yii ni opopona ni Ibadan lai bẹru Corona Virus

Àkọlé àwòrán,

Tọkunrin tobinrin lo n wọnu ọja lati ra nkan sile nitori bi igboro ṣe ri lori ọrọ Corona virus

Àkọlé àwòrán,

Ẹ wo awọn eeyan ti wọn n wo fuu pe wọn ko mọ ohun to ku

Àkọlé àwòrán,

Oṣiṣẹ ile ifowopamọ kan ree to n fun awọn onibara ni ohun eelo wiwẹ ọwọ ṣaaju ki wọn to wọ ile ifowopamọ

Àkọlé àwòrán,

Awọn oṣiṣẹ ọlọkọ ero ni Ibadan ree ti wọn duro gbagba ti ara wọn lopopona.

Àkọlé àwòrán,

Awọn ero miran ree ti wọn fun ara wọn ni aaye laarin ara wọn ki wọn to wọnu banki