Arìnrìnàjò sí Libya ní iṣẹ́ agbẹjọ́rò ló wù òun, àmọ́ iṣẹ́ aṣẹ́wó ló mú ṣe ní Libya

Arìnrìnàjò sí Libya ní iṣẹ́ agbẹjọ́rò ló wù òun, àmọ́ iṣẹ́ aṣẹ́wó ló mú ṣe ní Libya
Sahara desert

Oniruuru iroyin lo ti n waye lori ohun toju awọn ọmọ Naijiria n ri lsna aṣalẹ ilẹ lọ sorilẹede Libya ati ni Libya gangana lọna ati jẹ ati mu.

Ifọrọwerọ yii wa pẹlu meji lara awọn ti wọn ti rin irinajo yii.

Ẹ woo bọdẹ ba roṣẹ to ro iya to jẹ ninu igbo bo ba pẹran ko ni fun ẹnikẹni jẹ lọrọ yii o