Wọ́n fi agídí sé ọmọ Naijiria mọ́lé ní China nítorí àrùn Coronavirus

Wọ́n fi agídí sé ọmọ Naijiria mọ́lé ní China nítorí àrùn Coronavirus

Ọmọ Naijiria kan to wa ni orilẹ-ede China sọ ohun toju rẹ n ri nilẹ ọhun nitori arun Coronavirus.

Ọkunrin naa sọ fun BBC pe wọn fi tipa tikuku gbe oun kuro nile oun lọ si ile iwosan nitori ibẹru pe awọn alawọ dudu lee ko arun naa ran awọn ọmọ ilẹ China.

O ṣalaye pe wọn ko fọwọ kan awọn ọmọ ilẹ Yuroopu ati Amẹrika to wa lọhun, ṣugbọn awọn alawọ dudu nikan ni wọn n dojukọ.

Ẹ wo fidio yii fun ẹkunrẹrẹ.