Coronavirus lockdown: Àwọn ọ̀nà tí ẹ le fi dun ara yín nínú lásìkò ìgbélé

Coronavirus lockdown: Àwọn ọ̀nà tí ẹ le fi dun ara yín nínú lásìkò ìgbélé

Ọpọlọpọ orilẹ-ede ati ilu ni ọrọ igbele tipa-tipa kan, nitori itankalẹ aarun coronavirus.

Ọpọ eniyan si ni ko ba lara mu, nitori pe ọmọ ṣiṣẹ́-ṣiṣẹ́ ni wọn, tabi ẹni ti igbeaye oju kan ko mọ lara.

Fidio yii n se atọka si oriṣiriṣi ọna ti awọn eniyan fi n dun ara wọn ninu lasiko iporuru ọkan ti coronavirus mu ba ọpọ eniyan.

Kaakiri agbaye si ni wọn ti fi awọn fidio naa ranṣẹ si wa.