Ǹkan ti ojú àwọn ènìyàn ń rí lágbàyé nítori ààrùn Covid-19

Ǹkan ti ojú àwọn ènìyàn ń rí lágbàyé nítori ààrùn Covid-19

Àìlówó lọ́wọ́, ebí àti òsì kìí ṣe ìsòrò orílẹ̀-èdè naijiria níkan.

Ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn jákèjádo ló sọ ǹkan ti wọ́n ń foju ri àti ìhà ti ìjọba wọ́n kọ si ọ̀rọ̀ wọ́n.

Ẹkúnrẹ́rk wà nínú fọ́ràn yìí