Coronavirus Cases in Africa: Ṣé lóòtọ́ọ́ nipé irọ́ n'ìjọba Nàìjíríà ń pa lórí ìtànkálẹ̀ ààrùn coronavirus?

Ṣe lootọọ ni pe ijọba orilẹede Naijira n parọ lori ajakalẹ aarun coronaviris?

Ọpọ ọmọ Naijiria lo gbagbọ pe irọ ni ijọba n pa lori ọrọ covid-19, wọn ni wọn kan fẹ fi ọrọ ajakalẹ aarun naa kowo jẹ ni.

Ẹ maa bawọn daṣa iru rẹ o, nitori otitọ ni pe aarun covid-19 wa ni Naijiria.

Ijọba ṣi n tiraka lati oogun si aarun naa to fi di bi a ti ṣe n sọrọ yii.

Ajọ WHO ni titakete si ara ẹni lo ṣe pataki bayii lati dena aarun covid-19.