Abidakun Oluwatobi Lebanon Slavery: Ẹ̀yìn àti àyà máa ń dùn mí lóru tí mi ò ní lè sùn

Abidakun Oluwatobi Lebanon Slavery: Ẹ̀yìn àti àyà máa ń dùn mí lóru tí mi ò ní lè sùn

Iṣẹ aje kuku lo sọ ọmọ nu bi oko ti Tobi fi ba wọn lọ si ilu Lebanon, ṣugbọn ọrọ kọ ori da ibomii.

Abidakun Juliana Oluwatobi jẹ ọmọ ilu Efon Alaye ni ipinlẹ Ekiti to wa lara awọn tajo dee Lebanon.

"Ti o ba ti de ọhun, bi igba pe o kan ta ara rẹ fun wọn ni".

Ibi to ti n ṣiṣẹẹ́ telọ l'Eko ni eeyan kan ti fi iṣẹ telọ kan naa lọ ọ ni oke okun to si gba pe oun yoo lọ.

O pẹ ki wọn to sọ ootọ fun un pe iṣẹ ọmọ ọdọ lo fẹ lọ ṣe

Ohun ti oju Oluwatobi ri, afi ki ẹ gbọ ọ lẹnu oni nkan gangan.