Ondo Election 2020: Gbogbo ọlọ́pàá wa ní ìdánimọ̀, kò sí aráàta tó lè wọ àárín wọn

Ondo Election 2020: Gbogbo ọlọ́pàá wa ní ìdánimọ̀, kò sí aráàta tó lè wọ àárín wọn

Bolaji Salami to jẹ komisọna ọlọpaa ipinlẹ Ondo ni awọn ti ni ọlọpaa to to ẹgbẹrun mẹtalelọgbọn ti yoo ṣiṣẹ lasiko idibo gomina ipinlẹ Ondo ti yoo waye lọjọ Satide.

"Ori omi ni o, oriilẹ ni o, gbogbo ẹ la ti ṣeto a dẹ ni ọlọpaa to to ṣe gbogbo iṣẹ yẹn".

Awọn oṣiṣ alaabo ni ẹni to ba ko ayederu ọlọpaa wọlu, wọn fi jofin.

Bakan naa gbogbo irinṣ to fi mọ ọkọ ofurufu ẹlikọpita atawọn nkan irisẹ ijagun lo ti wa nikalẹ.