Hounourable SOB Agunbiade:Ọ̀tọ̀ ni "Palliatives" ìjọba tí wọ́n jí

Hounourable SOB Agunbiade:Ọ̀tọ̀ ni "Palliatives" ìjọba tí wọ́n jí

Ọmọ ile aṣojuṣofin to n ṣoju ẹkun idibo Ikorodu nile igbimọ aṣojuṣofin ipinlẹ Eko kan ti iroyin tan kalẹ pe o fẹ fi awọn nkan iranwọ Covid-19 ṣe ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ iyẹn Họnọrebu SOB Agunbiade ti ni irọ patpata ni iroyin naa to tan ka gbogbo agbaye.