BBC Africa Eye: Níbo ni owó Crowd 1 ti wá? Níbo ni owó Crowd 1 ń lọ? ni ìbéèrè tí ọ̀pọ̀ ń bèèrè

BBC Africa Eye: Níbo ni owó Crowd 1 ti wá? Níbo ni owó Crowd 1 ń lọ? ni ìbéèrè tí ọ̀pọ̀ ń bèèrè

Crowd 1 gba igboro kan gẹgẹ bi ọna lati ri owo pajawiri ṣugbọn...

Akoroyin BBC Africa Eye, Ayanda Charlie ṣe iwadii lori bi Crowd 1 ṣe bẹrẹ ati ibi to de duro.

O ṣalaye ohun to ṣokunfa iwadii naa ati ohun ti Crowd 1 da le lori gan an.

Ayanda ṣe iwadii awọn to wa nidi ẹ ati ọna ti wọn fi n gba awọn eeyan.

Iṣẹ iwadii yii dahun awọn ibeere bii:

Nibo ni owo crowd 1 ti wa?

Nibo ni owo Crowd 1 n gba lọ?

Ati bẹẹ bẹẹ lọ.