Lori iro: Ká ni àwọn Òbí mi gbà fún mí, èmi àti Sunny Ade á jọ máa 'Compete- Baba Lórí irọ́

Lori iro: Ká ni àwọn Òbí mi gbà fún mí, èmi àti Sunny Ade á jọ máa 'Compete- Baba Lórí irọ́

Iro pọ- Ismail Joseph Alagbado

Ajihinrere Ismail Badmus Joseph ti ọpọ n pe ni Baba lori irọ sọrọ ilẹ kun fun BBC Yoruba.

O mẹnuba awọn nakn to ṣẹlẹ ti oun fi di oniwaasu.

Baba ẹni ọdun mejilelaadọrin naa sọ diẹ nipa nkan ti oju ohun ti ri laye, ọrọ kun ilẹ.

Baba Lori irọ ṣalaye pe Oluwa lo ran oun niṣẹ kii ṣe eniyan ati pe ọpọlọpọ ọdun ni oun ti n ṣiṣẹ iwasu yii laiboju wo ẹyin.

Baba tun sọrọ lori awọn to parọ n gba owo nitori Babab Lori irọ.

Baba Lori Irọ ni koda, oun ko mọ ẹni to ya fọnran fidio ti o sọ oun di eeyan pataki lawujọ yii rara.

Baba sọrọ niap irinajo aye rẹ ati ipa ti ẹmi Olorun n ko larti dari oun.