Akomolede ati Asa lori BBC: Olùkọ́ Bolanle Adekanmi kọ́ wa nípa oríṣíi Àròkọ Yorùbá tó wà

Akomolede ati Asa lori BBC: Olùkọ́ Bolanle Adekanmi kọ́ wa nípa oríṣíi Àròkọ Yorùbá tó wà

Oriṣi meje ni Arokọ Yoruba ni eyi ti Olukọ yannana nipa rẹ fun wa.

Eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba ni eto to tun jade yii.

Orisi aroko ni a n gbe yẹwo lonii.

Arokọ Alariyanjiyan ni koko ti a n gbe yẹwo ni pato.

Oríṣun àwòrán, others

Arabinrin Bolanle Adekanmi lati ile iwe St Anthony Grammar School, Ikoyi-Ikire ni ipinlẹ Osun ni olukọ wa fun toni.

Arokó Alariyanjiyan

Aroko Ajẹmọ isipaya

Arokọ Alariyanjiyan

Arokọ Onisọrọ-n-gbesi

Arokọ Asọtan

Arokọ Asapejuwe

Leta kikọ

Oríṣun àwòrán, others

Iṣẹ agbẹ dara ju iṣẹ olukọ lọ ni koko ti Arabinrin Bolanle Adekanmi fi kọ ni kikun nipa Arokọ Alariyanjiyan yii

Kini pataki agbẹ lawujọ Yoruba?

Kini pataki Olukọ lawujọ?

E wa kọ ẹkọ sii nibi...