Vitamin D àti Covid-19: Òótọ́ nípa àṣírí tó wà níbi òògùn yìí fún ìwòsàn Covid

Oogun vitamin d to tan bi orun

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Awọn iroyin ofege ati irọ gbode lori ọrọ Covid ati itọju rẹ. Sugbọn nigba miran iroyin ti ko tọna a maa jẹyọ ninu imọ to ni ootọ diẹ ninu, eyi si maa n nira lati koju.

Kini Vitamin?

Oniruuru ilana itọju ni àwọn eniyan ti pero lati koju aarun Covid-19.

Hydroxy chloroquine, Ivermectin ati Vitamin D - gbogbo rẹ ni wọn ti ṣe agbeyẹwo rẹ. Ti wọn si pete rẹ pe o le ṣiṣẹ, sugbọn ko si iwadii to ju ti ilana sayẹnsi lọ.

Ṣugbọn lori ayelujara awọn iwadii ti ko tẹwọn to ni awọn eniyan yoo maa pin ti awọn obayejẹ miran naa yoo si bẹrẹ si ni lo o ni ilodi.

Ariwisi le wa lori pe Vitamin D le wulo fun itọju tabi lati da abo bo eniyan lori Covid-19.

Vitamin D ni iṣẹ ribiribi lara eroja to n dabo bo ara ti ijọba ilẹ Gẹẹsi si ti ni ki gbogbo ọmọ ilu gba oogun rẹ to ba di asiko ojo, ki awọn to jọ pe wọn ko ni Vitamin D to pe lara maa lo titi ọdun yoo fi yipo. Sugbọn titi di asiko yii ko tii si ẹri aridaju pe Vitamin D le wo aisan kankan tabi dena rẹ, sugbọn ko tumọ si pe ko ni wulo lọjọ iwaju

Àkọlé fídíò,

Àwọn olúlùfẹ́ fí ìbòjú fi ẹnu ko ara wọn ní Philippine

Njẹ mo ni lati bẹrẹ si ni lọ Vitamin D?

O ye wa pe ọpọ awọn to n sọ ọrọ yii lori ayelujara bẹrẹ bi imọran ni. Sibẹ awọn miran tun gbe kọja ero yii, gẹgẹ wọn ṣe gbe soju opo Reddit pe ijọba ko tilẹ mẹnuba iṣẹ ribiribi ti Vitamin D n ṣe, sugbọn ti wọn gbajumọ ọrọ abẹrẹ ajẹsara ati bi ọlọpaa ṣe n tọ pinpin ara ilu bakan naa ni wọn tun naka wọn ko kọju mọ ọrọ Vitamin D nitori ajọ WHO ń gba owo lọwọ awọn ile isẹ apoogun nlanla8

Ṣugbọn ijọba ti lọ n moju to awọn ojuutu itọju miran ti owo rẹ ko gani lára bí dexamethasone ti aridaju wa fun nigba kan ati awọn Vitamin ti wọn n ri ọkẹ aimọye poun.

Kini iwadii sọ?

Ọpọ awọn iwadii lo ti fi asepọ han laarin Vitamin D ati Covid sugbọn iwoye olukuluku ni ẹri wọn- eyi tumọ si pe nkan ti o ba sẹlẹ si awọn to ni Vitamin D to pọ ati eyi to kere lai fi nkan miran kun ni ẹri olukuku.

Ẹri iwadii yii fi han pe awọn ipin mejeeji le ma ni anito vitamin D ti Covid is le mu wọn, awọn arugbo, awọn to sanra, ati awọn eniyan dudu.

Ko daju boya awọn eniyan yii ni ipenija miran ninu agọ ara wọn ni ó tabi ayika wọn lo jẹ ki wọn ni aarun Covid-19 gbogbo naa lo lo Vitamin D ti wọn si le ni arun Covid-19

NHS gba awọn eniyan dudu niyanju " bi apẹẹrẹ awọn afirika, afirika ti Caribbean, South Asian lati gba Vitamin D ti ọdun yoo fi pari.

Abajade ti Spanish ni sọ pe diẹ ni aseyọri Vitamin D pẹlu ida ọgọrin eniyan lati bọ lọwọ yara itọju pajawiri ati adinku ida ọgọta ninu iku Covid.

Àkọlé fídíò,

Jimoh Ológì déé! Ọ̀mọ̀wé ní kílàsì fásitì, ológì nílé

Ewu to wa nibẹ

Nigba ti iwadii jade pẹlu iwoye awọn eeyan lagbaye fun apr pe awọn nkan ti Ọlọrun da ko lee pa ẹ lara" Ọjgbn Sander Can der Linden ni fasiti Cambridge ṣalaye pe eyi lo maa n jẹ ki awn eeyan maa pin in kiri.

Ẹwẹ, o ni ọrọ ori ayelujara nipa awn nkan ti lẹdaa da fun ilera atawọn oogun mii to fi mọ iwoye awọn eeyan ni ilodi si gbigba abẹrẹ ajẹsara naa n peleke sii.

Titako gbigba abẹrẹ yii ti lọ mọ ọrọ sin, oogun ibilẹ atawọn oogun mii gẹ́gẹ́ bi Ọjgbọn Van ṣe sọ ọ.

O ni ko sewu ninu Vitamin D bo tilẹ jẹ pe awọn ogun oyinbo kan wa ti ko b lwọ ewu tiwn paapaa to ba ti pọ ju) torinaa iroyin pe ki awọn eeyan rra ṣe ko fi gbogbo ara jẹ ipalara.

Ọjọgbọn Van der Linden ṣalaye pe ewu to wa nibẹ ni ki awọn eeyan maa dabaa pe lilo Vitamin D n ṣe iṣẹ ami ati iṣẹ iyanu torinaa ki wọn maa lo o dipoo ibomu àti itakete sira ẹni.