Seyi Makinde: Ẹ̀yin tẹ́ fẹ́ fi ọ̀rọ̀ ẹ̀sin ba Oyo jẹ́, ẹ ṣọ́ra ṣe

Seyi Makinde: Ẹ̀yin tẹ́ fẹ́ fi ọ̀rọ̀ ẹ̀sin ba Oyo jẹ́, ẹ ṣọ́ra ṣe

Seyi Makinde ti yarí lórí báwọn aṣọ́bode ṣe ń wọ ìpínlẹ̀ Oyo láì bun gbọ́.

Bakan naa lo fi ọrọ ransẹ si awọn eeya to fẹ fi ọrọ ẹsin da ipinlẹ Oyo ru.

Gomina Seyi Makinde sọrọ yii nigba to n bawọn akọroyin sọrọ lasiko ọdun Ileya.