Test your Yoruba language skill: Wá ká jọ sọ Yorùbá...

Test your Yoruba language skill: Wá ká jọ sọ Yorùbá...

Ọbẹ Bàbá bọ́, ó bá ọbọ Ọba....Sẹ ẹ ṣì rántí ọjọ́?

Ki ede Yoruba ma baa parun ni BBC Yoruba se jade lọ beere ibeere lọwọ awọn eeyan loju popo.

Pe ki wọn yara pe awọn ọrọ akọnilẹnu.

Obe Baba bọ, o ba ọbọ Ọba ni ọpọ igba.

Eyin naa le gbiyanju ẹ nibi ti ẹ wa, o ya!