Osun at 30: Gomina Adegboyega Oyetola ni ọbẹ̀ ìpínlẹ̀ Osun ti di àtúnse lẹ́yìn ọgbọ́n ọdún ti a dá a sílẹ̀

Osun

Oríṣun àwòrán, @Osun

Lọdun 1991 ni aarẹ Naijiria nigba kan ri, Ibrahim Badamosi Babangida da a sile pẹlu a\won ipinlẹ mii bi Enugu.

Lati ara ipinlẹ Oyo ni wọn ti yọ Osun kuro ti wọn si sọọ ni orukọ odo Osun Osogbo pẹlu ilu Osogbo gẹgẹ bii olu ilu rẹ.

Leyin ọgbọn ọdun yii ni Gomina Adegboyega Oyetola to n tukọ rẹ lasiko yii ni pe iyan rẹ ti di ti atungun bayii.

Oyetola ni ọkan lara ohun tuntun lati ṣe ni lati sọ ipinlẹ naa di ti eyi to n pese iṣẹ yatọ si iṣẹ ijọab nikan ti a mọ wọn mọ.

Oyetola sọ eyi lasiko to n ba awọn akoroyin sọrọ lori eto olosoosu nile iṣẹ iroyin OSBC ti ipinlẹ Osun.

O ni ijọba ti n mu ayipada de ba okowo ati iṣẹ pipese sii.

Àkọlé fídíò,

Rape survivor: Ìyá mi ni ń kò gbọdọ̀ sọ̀rs kí ilé má bà á dàrú- Oluwatobi Raji